IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday, 20 June 2020

ALAGA IJOBA IBILE IDAGBASOKE, ONAREBU FATAI AJIDAGBA DERIN PEEKE AWON EEYAN IJOBA IBILE E

Senken ninu awon eeyan ijoba ibile idagbasoke Ifelodun n dun pelu alaga ijoba ibile naa, Onarebu Fatai Shuiab Ajidagba ti gbogbo eeyan mo si Ajifat se fi ero amomi tutu nla tawon lore.
Alaga tawon eeyan feran daadaa yii se eyi lati fi ran okoowo awon eeyan e yii lowo. Gbogbo won pata ni won dupe lowo e fun oore nla to se fun won yii



No comments:

Post a Comment

Adbox