• GBAGEDE WA
  • NIPA WA
  • E KAN SI WA

IROYIN OJUTOLE

  • Home
  • OJUTOLE-TOKO
  • _NIPA WA
  • _IPOLOWO
  • IROYIN
  • LAGBO OSERE
  • ORO TO N LO
  • OSELU
  • ISELE KAYEEFI
  • FUN IPOLOWO +2348080597807

IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 6 May 2020

Home / LAGBO OSERE / Pataki ni ibalopọ jẹ laarin ọkọ ati iyawo, ṣugbọn awọn ojiṣẹ Ọlọrun ki i sọrọ nipa ẹ-Mosun Filani

Pataki ni ibalopọ jẹ laarin ọkọ ati iyawo, ṣugbọn awọn ojiṣẹ Ọlọrun ki i sọrọ nipa ẹ-Mosun Filani

by IROYIN OJUTOLE on May 06, 2020 in LAGBO OSERE

Ọkan pataki ninu awọn oṣere tiata Yoruba ti ogo rẹ buyọ daadaa ninu iṣẹ naa ni Arabinrin Mosunmọla Filani Oduoye, odu lobinrin naa ninu awọn elere ori itage wa ki i ṣaimọ foloko rara.   

Kinni kan ti arẹwa oṣere yii fi yatọ sawọn kan lagbo awọn elere wa ni pe ile ọkọ lo wa, bẹẹ lo jẹ ọkan pataki ninu awọn oṣere ti wọn jẹ iyawo ile tawọn yooku n wo lawokọse rere, obinrin yii niyawo gbajugbaja oloselu nipinlẹ Ọṣun, iyẹn Ọnarebu Simeon Oduoye, o si ti to ọjọ mẹta ti wọn n ṣe tọkọ-taya . Nitori ẹ la ṣe wa Mosun kan, a fẹ ko gba obinrin, paapaa awọn ti ko i lọ sile ọkọ nimọran ọna ti wọn yoo gbe e gba ti wọn yoo fi rile ọkọ gbe bii tiẹ atawọn to wa nibẹ ti igbeyawo wọn yoo fi dalẹ .

Diẹ ninu ohun ti oṣere nla ọhun ba wa sọ ree, ẹ ma a ba wa ka lọ.

Gẹgẹ bii iyawo rere lọọdẹ ọkọ, a fẹ ki ẹ gba awọn obinrin niyanju ọna ti wọn yoo gba rile ọkọ gbe, paapaa bo ṣe jẹ pe igbeyawo ko tọjọ mọ to fi n daru lasiko yii

Ẹ ṣeun  ohun akọkọ ti mo fẹ ki ẹ mọ ni pe ko si ibi ti ajalu tabi iṣẹlẹ buruku ki i ti waye,  adura ti a o ma a gba ni pe ki Eledua ṣaanu fun wa,  ki iṣẹlẹ laabi  ma de ọdọ wa. Ki i ṣe igbeyawo awọn onitiata nikan lo ma n daru, ti ẹ ba wo awujọ wa daadaa, ẹ o ri i pe ikọ-ni- silẹ ti di tọrọ-kọbọ bayii,  koda o ti fẹẹ da bii nnkan ti o dara tabi ti ko buru rara ni. Ọpọ nnkan lo rọ mọ iṣẹlẹ yii, ile awọn dokita, adajo, amojuẹrọ, awọn olukọ, awọn oniṣẹ ọwọ ati bẹẹbẹẹlọ n tuka,  nitori iṣẹ ti awa yan laayo lo fi dabii ẹni pe nnkan ri bo ti ri lọdọ wa, tawọn eeyan ma n wo awa obinrin elere ori itage bii ẹni ti ko fẹ gbe ile ọkọ.

Ki lẹ ro pe o n fa a?

Nnkan to fa a pọ gan-an,  ẹ jẹ ka bẹrẹ bayii,  pupọ ninu rẹ wa lati inu ile ti  a ti jade. Awọn ọmọbinrin nikan ni pupọ ninu awọn obi wa maa n kọ bi wọn o ṣe lo ọjọ iwaaju wọn nile ọkọ, ti wọn si maa n gbagbe pe ninu igbeyawo ati ọkunrin ati obinrin ni wọn jọ ni ojuse to pọn dandan lati ṣe. Bibeli gan-an sọ nipa ojuṣe ọkunrin ati obinrin, oluranlọwọ ara wa la jẹ, ṣugbọn ọmọ obinrin nikan lo ma n gba itọsọna ninu igbeyawo, eyi ti a le sọ pe obinrin nikan lo n kọ ati imọ to peye lati wọ inu igbeyawo lọpọ igba, eyi ko tunmọ si pe gbogbo iya ni ko kọ awọn ọmọkunrin wọn, ṣugbọn ko fi bẹẹ wọpọ.

Ọna mi-in to tu n da igbeyawo ru ni pe pupọ ninu awọn ọkọ ti gba pe gbogbo iṣe ile iyawo lo gbọdọ ṣe  e, omiran ninu wọn yoo na ẹsẹ sori tabili ti yoo ma a wo ẹrọ amohumaworan, ọkunrin mi-in ko mọ bi wọn ṣe n ki iyawo ku iṣẹ, wọn o ma a wuwa bii ologun ni.

Awọn ẹbi, ara adugbo, awọn ọrẹ kun awọn ohun to n da igbeyawo ru, ẹlomi-in nnkan ti ko kan wọn yoo ma a da si i, ti ọrẹ mi ba gba ọrẹ rẹ nimọran lori igbeyawo rẹ ẹru Ọlọrun yoo ba yin nitori pe pupọ ninu nnkan to n gba ni ile tiẹ lọdọ iyawo ẹ ni yoo sọ  pe oun ko le e gba. Awọn onimọran ika ni wọn kun ode bayii, pupọ ninu wọn ni da bi mo ṣe da, ọpọ ọrọ lo ti gba ọkọ ọrẹ. Ẹ jẹ ka wo awọn aburo ati awọn ẹgbọn ọkọ, nigba miiran wọn o ki fi iwa wọn ran idile lọwọ ìlù kówókówó ni pupọ ninu wọn maa n hu. Awọn ẹbi kan dara o, ṣugbọn awọn ti ko dara pọ  ju awọn ẹbi to dara lọ.

Pataki ni ibalopọ jẹ ninu igbeyawo, pupọ ninu awọn ojiṣẹ Ọlọrun nile ijọsin ati awọn oludanilẹkọọ awọn idile ni wọn ki i mojuto ọrọ yii ki lọkọ laya too di ọkan wọn gbọdọ mọ nipa bi ara wọn ṣe gbe wọn si, obinrin mi-in ọkọ rẹ ko lagbara ju ọgbọn iṣẹju lọ, ṣugbọn iyawo mi n fẹ wakati mẹta, bawo ni wọn ṣe fẹẹ ṣe e? Ọ
kunrin mi-in naa  fẹran ibasun gidi gan-an,  ti iyawo ko si fẹran iru nnkan bẹẹyẹn.  Wahala niru nnkan bẹẹ yoo da silẹ ninu ile.

Ọkunrin ati obinrin ti wọn ba fẹ ki ile won toro ti gbọdọ mọ bi kaluku ṣe gbadun ibalopọ si. Ọrọ pọ ninu iwe kọbọ, ohun to n fa wahala pọ gan-an, ṣaaju ati ninu igbeyawo, idile kọọkan si yatọ sira wọn, nitori ohun ti Taye gba, Kẹhinde le ma le gba.

Ẹ ba wa gba awọn tọkọ-taya nimọran

Mo  fẹ ki awọn ọkọ alalubarika ki wọn mu itọju ile wọn ni okunkundun, ki wọn o si ma gbe iyawo wọn lọkan soke, awọn ọkunrin ti aye ati ọrun yoo yẹ, awọn ti ọjọ wọn yoo dalẹ.
Ko si igba ti eeyan ko le yi pada, aye si wa fun atunṣe fun awọn ọkunrin ti ko ṣe daadaa ninu ile wọn.

Mo kan saara si awọn obinrin ti wọn ni iwa irele ti wọn ba ọkọ wọn fara da a ati awọn to jẹ pe awọn ni ẹru ile wọ lọrun, mo fẹ ki wọn ni igbagbo pe yoo dara lọjọ kan. Mo fi asiko yii naa ki ọkọ mi o, a du ma a dan ọmọ wọn ni Ikirun Agunbẹ Onile obi, ọmọ ẹlẹni atẹẹka, ọmọ ẹlẹni ẹwẹlẹ. Ọlọrun yoo ma a tunbọ ṣalekun oore rẹ.  Mo nifẹẹ rẹ ade ori mi.

Tags # LAGBO OSERE
Whatsapp
Author Image

Nipa IROYIN OJUTOLE
NJE O NI IROYIN FUN WA BI? TABI O NI AYEYE TI O FE KI A BA O GBE JADE? ABI IPOLOWO OJA TABI IKEDE LE FE SE, TETE PE SORI AWON NOMBA WONYI: 08023939928, 08185819080.

Related Posts:
LAGBO OSERE
By IROYIN OJUTOLE on - May 06, 2020
Email ThisBlogThis!Share to XShare to FacebookShare to Pinterest
Tags LAGBO OSERE

No comments:

Post a Comment

Newer Post Older Post Home
Subscribe to: Post Comments (Atom)

KI LE N WA?

KARI AYE NI WON TI N KA A

Live Visitors Counter
Powered by Blogger.

AWON TO TI KA OJUTOLE-TOKO

Featured

E KAN SI WA 08080597807

Name

Email *

Message *

Most Popular

  • Ija ilara lawọn to  n sọ isọkusọ nipa mi, emi o ri ti wọn ro-Oniroko tiluu Iroko
    Ija ilara lawọn to n sọ isọkusọ nipa mi, emi o ri ti wọn ro-Oniroko tiluu Iroko
    Ọba Oluṣẹgun Ayinde Feyijinmi Iroko, Oniroko tilu Iroko, nijọba ibilẹ Ado-Odo-Ọta, nipinlẹ Ogun, ti sọ pe ija ilara loun ka gbog...
  • GNI pn ounjẹ fawọn alaawẹ ni wọn ba n fadura ranṣẹ si i
    GNI pn ounjẹ fawọn alaawẹ ni wọn ba n fadura ranṣẹ si i
    Titi di akoko ta a wa yii lawọn araalu fi adura ranṣẹ si Ọnarebu Gboyega Nasir Isiaka ti wọn tun pe ni GNI, to n ṣoju agbegbe Im...
  • Yoruba lo yẹ ko jẹ aṣaaju nipa fila ati gele lagbaaye- Alake tilẹ Ẹgba
    Yoruba lo yẹ ko jẹ aṣaaju nipa fila ati gele lagbaaye- Alake tilẹ Ẹgba
    Alake tilẹ Ẹgba, Ọba Adedọtun Arẹmu Gbadebọ, ti ṣapejuwe Yoruba gẹgẹ bii aṣiwaju laarin awọn ẹya gbogbo kaakiri agbaye, paapaa, ...
  • Rotimi George-Taylor dẹru jẹjẹ sawọn oludije sẹnetọ yooku lọrun  lOgun Central.Wọn ko mọ ọna ti yoo gba yọ si wọn
    Rotimi George-Taylor dẹru jẹjẹ sawọn oludije sẹnetọ yooku lọrun lOgun Central.Wọn ko mọ ọna ti yoo gba yọ si wọn
     Ki i ṣe tuntun mọ pe Ọnarebu Rotimi George Taylor ni ẹgbẹ oṣelu Nigerian Democratic Congress iyẹn NDC fun ni tikẹẹti oludije fu...
  • Eyi lohun ti Iyayẹmi Ẹlẹbuibọn sọ nipa obinrin to n fi inu meji ba ọkọ lo
    Eyi lohun ti Iyayẹmi Ẹlẹbuibọn sọ nipa obinrin to n fi inu meji ba ọkọ lo
    Àràbà Awo ilẹ Oṣogbo. Araba Ifayẹmi Ẹlẹbuibọn, ti ṣalaye ewu to wa fun iyawo ile ti ko jẹ oloootọ si ọkọ...
  • Alaimọkan lo n sọ pe ayẹyẹ ọjọọbi Anọbi ko ṣe pataki- Al-Khaleefah Ọlọrunṣẹyẹ.
    Alaimọkan lo n sọ pe ayẹyẹ ọjọọbi Anọbi ko ṣe pataki- Al-Khaleefah Ọlọrunṣẹyẹ.
       Fadilat Sheikh Al-Khaleefah Abdul Quadri Ishọla Ọlọrunṣẹyẹ, to jẹ oludasilẹ ileewe JAMHYAT NUUR SOMODANY AL-ISLAMY FOUNDATION...
  • Erongba wa ni lati ṣaaju awọn ọmọ orileede yii wọ ilẹ ileri lọdun 2027- Arẹgbẹṣola
    Erongba wa ni lati ṣaaju awọn ọmọ orileede yii wọ ilẹ ileri lọdun 2027- Arẹgbẹṣola
    Ọgbẹni  Rauf Arẹgbẹṣọla, akọwe fẹgbẹ ADC lapapọ ti sọ pe erongba wọn...
  • Tunde Lẹmọ ọna tooro to wọ Oke-Mọsan lọdun 2027
    Tunde Lẹmọ ọna tooro to wọ Oke-Mọsan lọdun 2027
    Bi ojumọ ṣe n mọ bẹẹ ni eto oṣelu fun ibo ọdun 2027, sunmọ etile tawọn araalu si ti n woye ẹni ti wọn yoo dibo wọn fun gẹgẹ bi a...
  • O tan:Alaga APC tẹlẹ ni Enugu atawọn ọpọ eeyan darapọ mọ ADC
    O tan:Alaga APC tẹlẹ ni Enugu atawọn ọpọ eeyan darapọ mọ ADC
    A fi bii awọro lọrọ naa jẹ nipinlẹ Enugu, nigba ti alaga fẹgbẹ oṣelu APC tẹlẹ, Ọgbẹni A C Udeh ati olori awọn obinrin,Lolo Nwakw...
  • Ó ṣẹlẹ,Arẹgbẹṣọla ati Gbadebọ Rhode-Vivour fẹẹ fi ẹgbẹ ADC gbajoba   Eko lọwọ   Tinubu ati APC
    Ó ṣẹlẹ,Arẹgbẹṣọla ati Gbadebọ Rhode-Vivour fẹẹ fi ẹgbẹ ADC gbajoba Eko lọwọ Tinubu ati APC
    Pẹlu bí  idibo ọdun  2027ṣe n sunmọ etile ẹgbẹ African Democratic Congress, ADC ti mura lati gba iṣakoso ipinlẹ Eko kuro lọwọ Aa...

Labels

  • BO SE N LO
  • IROYIN
  • KAYEEFI
  • LAGBO OSERE
  • ORO TO N LO
  • OSELU
Adbox

BO SE N LO

ipolowo oja

IROYIN TO GBAJUMO

Created By SoraTemplates | Distributed By Blogger Templates