IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Monday 1 April 2019

ONI LAYEYE OJOOBI IFAKALELUYAH,E JE KA KI EBORA OMO TI N GBENU RADIO DUN YANMUYANMU KU ORIIRE

Gbogbo wa pata nileese Ojutole la ki eeyan wa daadaa, gbajugbaja sorosoro ori radio to gbayi kari aye,
Ambasado, Dokita Abdulyomi Mate ti gbogbo aye mo si Ifankaluyah ku oriire ayeye ojoobi e to waye loni-in. 

Adura wa fun omo olojoobi ni pe ko se opo odun laye ninu ola, owo ati alubarika repete.
Igba odun, iseju aaya ni.

No comments:

Post a Comment

Adbox