Gongo yoo so lojo Abameta, Satide to n bo yii, ojo naa ni Oba ilu Oruba Awori yoo jawe oye le okan lara awon ogbontarigi osise ileese Radio Lagos, Alaaja Adeola Kifayat Orisile lori gege bii Erelu Afedesewa ilu naa.Awon eeyan jankanjakan lawujo ni won yoo peju-pese ba Orisile sayeye nla yii. Ewe oye yoo mori o.

No comments:
Post a Comment