Bakan naa lo lu ajo eleto idibo logo enu fun bi won seto idibo naa, ti gbogbo e lo daadaa, la i si wahala kankan. O wa a dupe lowo awon eeyan e niluu Ikorodu fun bi se jade lati dibo fun gbogbo awon
Okan pataki ninu awon onisowo nla nipinle Eko, Otunba Kamorudeen Lamina ti gbogbo aye mo si Sir Kay Oluwo ti gbe osuba o kare laye fawon olugbe Eko fun bi won se jade lati dibo fun egbe oselu APC. Gbajumo onisowo yii lasiko to n ba Ojutole soro nibudo ibo e, o ni ko si wahala kankan lawon ibudo idibo to n mujo. Lati aaro lo so pe awon oludibo ti jade, ti ko si wahala kankan rara, ti ohun gbogbo lo ni woroowo.
Bakan naa lo lu ajo eleto idibo logo enu fun bi won seto idibo naa, ti gbogbo e lo daadaa, la i si wahala kankan. O wa a dupe lowo awon eeyan e niluu Ikorodu fun bi se jade lati dibo fun gbogbo awon
oludije omo egbe APC.
Bakan naa lo lu ajo eleto idibo logo enu fun bi won seto idibo naa, ti gbogbo e lo daadaa, la i si wahala kankan. O wa a dupe lowo awon eeyan e niluu Ikorodu fun bi se jade lati dibo fun gbogbo awon
No comments:
Post a Comment