Gbogbo awon eeyan ti won ti gbo rekoodu tuntun tawon gbajumo osere fuji meji, Mayor Akeem Alamu to fi orile-ede Amerika sebugbe ati Alaaji Taye Currency gbe jade ni won kan saara si ise opolo. Won ni orin ologbon ati alujo to ki popo lawon irawo osere fuji naa ko sinu rekoodu tuntun ti won pe ni 'Destiny'.
Ileese S.Gold la gbo pe o gbe rekoodu yii jade. Bawon ololufe orin fuji se le ri rekoodu yii ra ni Naijiria, bee ni won yoo ri i ra lorile-ede Amerika. Lara ibi ti won yoo ti ri rekoodu yii ra nii Southwest Farmers Market, 9801, Bissonet Street, Amala Zone 14815, Westerner Road, Houston Texas 77083, Onala African Stores 7863, Highway 65, Houston Texas 77083, S Gold Music, Shop Ey 5and 6, Abuja Plaza, Alaba International Market ati gbogbo ibi ti won ti n ra ojulowo rekoodu.
Lasiko ton ba wa soro,Mayor Alamu ro gbogbo awon ololufe e lati ra rekoodu tuntun to sese jade yii, o ni won ko ni i kabaamo pe won ra a.

No comments:
Post a Comment