Ti won ba n mu awon arewa obinrin lorile-ede yii, ohun to daju saka ni pe won ko ni i rin jina rara ti won yoo fi daruko Arabinrin Mutiyat Abidemi Kolawole si i, omobinrin naa dara bii egbin o jare.
Inu wa dun, ara wa si ya lati so fun gbogbo eyin ololufe Outole pe oni-in layeye ojoobi omo bibi Ila-Orangun, nipinle Osun yii, nitori e ni la n se ba a dupe lowo Olorun.Yato si pe Abidemi je omowe,to kawee jade nileewe yunifasiti, telo ni tabi ka so pe fason disaina ni, o mo nipa ise aso riran bii ka a-si-nnkan. O ya omo olojoobi, ijo lese e.


No comments:
Post a Comment