IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday 13 January 2019

ONI LOJOOBI WOLII FEMI OKIKIOLA,E JE KA KI OJISE OLORUN KU ORIIRE

Gbogbo wa pata nileese Ojutole la ki ojise Olorun Alaaye, baba ti wa daadaa, Prophet Femi Okikiola fun ayeye ojoobi won to waye loni-in. Ki Olorun je ki baba se opolopo odun laye ninu ola,owo, alaafia ara. Ki ajinde ara o maa je sir.

No comments:

Post a Comment

Adbox