Gbogbo wa pata nileese Ojutole la ki ojise Olorun Alaaye, Eni-Owo Oluwaseun Oluwatunmibi ku ayeye ojoobi won to waye. Adura wa fun won ni pe ki won se opo odun laye ninu ola, owo, alaafia to peye ati irorun nla. Igba odun,iseju aaya ni sir.
No comments:
Post a Comment