Thursday, 31 January 2019
E JE KA BA AARE EGBE IYA-N-GHANA FANS CLUB SAYEYE OJOOBI E
Tags
Nipa IROYIN OJUTOLE
NJE O NI IROYIN FUN WA BI? TABI O NI AYEYE TI O FE KI A BA O GBE JADE? ABI IPOLOWO OJA TABI IKEDE LE FE SE, TETE PE SORI AWON NOMBA WONYI: 08023939928, 08185819080.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
A ba aare egbe Iya-n-Ghana Fans Club, Alaaja Jejeola Muinat Adedayo dupe lowo Olorun fun ayeye ojoobi won to waye loni-in. Olorun yoo je ki won se opo odun laye ninu ola, owo ati alaafia ara. Igba odun, iseju aaya ni

No comments:
Post a Comment