IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Thursday 31 January 2019

AJIYINRERE BAYO EMERALD LO N SOJOOBI, E JE KA BA A DUPE LOWO OLORUN

A ba eeyan wa pataki, gbajugbaja olorin emi nni,Ajiyinrere Bayo Emerald dupe lowo Olorun fun ayeye ojoobi e to waye loni-in. Adura wa ni pe ki omo olojoobi sopo odun laye ninu ola, owo, igbega ati alaafia.

Gbogbo wa pata nileese Ojutole la ki yin ku oriire, igba odun,iseju aaya ni.

No comments:

Post a Comment

Adbox