Gbogbo wa pata nileese Ojutole la ki baba wa daadaa, agba-oje olorin juju nni, Profeso YK Ajao, ku oriire ayeye ojoobi won to waye loni-in. Adura wa ni pe ki Alagba Yekinni Oladeni Y.K Ajao se opolopo odun laye ninu ola, owo, arisiiki repete ati alubarika. Hapi Batide.

No comments:
Post a Comment