IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday 21 November 2018

GBAJUMO OLORIN ISLAM, HAJIA SHIKURAT AKOBI-AYELOYUN FEE FUN IFAKALELUYAH ATI IYA -N-GHANA LAMI-EYE, O TUN FEE KO REKOODU TUNTUN JADE

Ojo kerindinlogun osu kejila, odun yii  ni gbajugbaja olorin Islam nni,  Hajia Shukurat Wazzi tawon eeyan mo si Akobi-Ayeloyun fee sayeye nla l'Ekoo. 


Ayeye ohun ni ifilole rekoodu tuntun, ifilole ajo 'Akobi-Ayeloyun Music International' ati sise eye nla fun gbajugbaja sorosoro ori radio ati telifisan, Ambasado Yomi Mate ti gbogbo aye mo si Ifa-kale-luyah ati ilu mo on ka olorin Islam nni, Alaaja Bashirat Ogunremi ti won tun n pe ni  Iya-n-Ghana.

IYA-N-GHANA

Gbongan 'Amje Event Centre' to wa ni Amje Busitoopu, loju-ona marose Eko s'Abeokuta layeye naa yoo ti waye. 

Aso kampala elegberun merin naira lawon eeyan yoo fi wole sibi ayeye nla yii.  

.



No comments:

Post a Comment

Adbox