Oni layeye
ojoobi gbajugbaja olorin Islam nni,Queen Seidat Almubarq, gbogbo wa pata nileese Ojutole la ki eeyan wa pataki ku oriire, adura wa fun Queen of zikir ni pe ko se opo odun laye ninu ola,emi gigun, arisiiki ati alubarika repete.
Nipa IROYIN OJUTOLE
NJE O NI IROYIN FUN WA BI? TABI O NI AYEYE TI O FE KI A BA O GBE JADE? ABI IPOLOWO OJA TABI IKEDE LE FE SE, TETE PE SORI AWON NOMBA WONYI: 08023939928, 08185819080.

No comments:
Post a Comment