IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Thursday, 11 October 2018

KAYODE JINAD, OGA ILEESE KGN LO SOJOOBI, E JE KA KI I KU ORIIRE

Gbogbo wa pata nileese Ojutole Online Media la ki eeyan wa daadaa, Ogbeni Kayode Jinad, oga ileese Global Nation, ku oriire ayeye ojoobi won to waye loni-in. Inu wa dun lati darapo mo awon ololufe won sajoyo yii.

A gba a ladura pe ki omo olojoobi sopo odun laye ninu ola, owo, alubarika ati igbega nla. A yo fun yin, a yo fun ara wa. Igba odun,
iseju aaya ni 

No comments:

Post a Comment

Adbox