Gbogbo omo Yoruba pata, a ku oriire o, Oonirisa, Oba Babatunde Eniitan Ogunwusi Ojaja 1 ti niyawo tuntun, won si ti se gbogbo etu to ye lori Olori tuntun yii. Oruko Olori tuntun yii ni Moronke Naomi Silekunola Ogunwusi.
A gbo pe wolli nla, afadura-jagun ni Olori tuntun yii, bee ni won so pe ife to gbona girigiri lo wa laarin oun ati Onirisa.
Gbogbo awon eeyan ti won ti gbo nipa iroyin ayo yii ni won ti n ba Oba Alaye dupe lowo Olorun fun oore ayo to sele si i yii.
No comments:
Post a Comment