IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Thursday, 18 October 2018

E WO WON, AWON OBINRIN ONITIATA TI WON LOMU NLA





Bose Arowosegbe: Osere yii naa ko kere ninu awon osere tiata Yoruba ti won lomu nla. Nitori e lawon ore e se ma a n pe e ni Anikisaya. Osere ti oko e je oga olopaa yii naa ki i fi i bo o pe omun oun tobi daadaa.Image result for Bose Arowosegbe and  her big boobs

Gbogbo awon osere ti a mu wa fun yin ni won loruko daadaa, bee ni won tun rewa, ti won si nimo daadaa nidii ise ti won yan laayo, sugbon kinni kan to mu won yato sawon osere egbe won ni pe omun won tobi daadaa, bee lawon naa ko fi bo pe Olorun jokun oyan nla fawon.Die ninu awon obinrin onitiata ti oyan won tobi la mu wa fun yin. 
Image result for Ronke Oshodi Oke and her big boobs


Ronke Osodi Oke: Lojokojo ti won ba n soro awon obinrin onitiata ti won lomu nla, o daju saka pe won yoo daruko Ronke Oshodi Oke si i. Nitori omun nla to ni yii, lo je ki won ma a pe e ni Osodi Oke, oun naa ki i fi i bo pe omun oun tobi daadaa.   


  

Ronke Odusanya: Obinrin yii ti won n pe ni Flack Ididowo naa wa lara awon osere ti won lomu nla. Ronke naa ma a n so ninu awon oro e pe oun naa lomu nla.Image result for Ronke Odusanya and  her big boobs
  

Bimbo Thomas: Nigbakigba ti won ba n daruko awon osere tiata Yoruba ti won lomu nla, won yoo daruko osere yii si i. Image result for Bimbo Thomas and  her big boobs 

Bisola Badmus: Osere to bimo fun oga awon onifuji, Alaaji Wasiu Ayinde yii naa lomun daadaa. Eni to ba ri awon foto Bisola to wa lori ero ayelujara yoo mo pe osere Olorun fomu nla ke e. Image result for Bisola Badmus and  her big boobs


Eniola Badmus: Ko si bi won yoo se soro awon obinrin onitiata to lomun nla ti won ko ni i daruko osere yii si i. Eniola naa wa lara awon obinrin onitiata ti won lebun omu nla.Image result for Eniola Badmus and  her big boobs 

Foluke Daramola: Osere to kawee gboye nileewe giga Obafemi Awolowo yii wa lara awon obinrin onitiata ti Olorun jokun oyan nla.Image result for Foluke Daramola and  her big boobs

Omowunmi Ajiboye: Iyawo Segun Ogugbe yii naa wa ninu awon obinrin onitiata ti oyan won tobi daadaa. Ko si bi won yoo se mu awon obinrin onitiata ti omun re tobi ti won ko ni i mu osere yii si i. Image may contain: 1 person

Sikiratu Sindodo: Osere yii toruko re gangan n je Khadijat Temitayo Odueke naa wa lara awon obinrin onitiata ti oyan won tobi daadaa. Awon kan tie so pe nitori omu e to tobi yii ni gbajumo osere fuji kan se kenu ife si i, ti won si fe ara won ko too di pe aarin won daruImage result for Sikiratu Sindodo and  her big boobs

Funke Adesiyan: Loooto omun obinrin yii ko tobi pupo tele, sugbon lojiji ni kinni ohun tobi, ohun tawon to mo osere yii so ni pe o lo oogun to maa n je ki omu tobi ni. Lojumo to mo loni-in, okan ninu awon obinrin onitiata ti oyan won tobi daadaa ni Funke wa.Image result for Funke and his big boobs 

Tope Osoba: Arewa osere yii naa wa ninu awon obinrin onitiata ti omun won tobi daadaa. Ko si bi won yoo se daruko awon obinrin onitiata to loyan, ti won ko ni i daruko obinrin yii si i.Image result for Tope Osoba and  her big boobs

No comments:

Post a Comment

Adbox