Ojo kokanla, osu kokanla odun yii lokan ninu awon omo gbajumo ori radio ati telifisan nni, Alaaja Kudirat Ashani Olayinka, iyen Abdulmalik Ramadan Akorede Sanni, yoo kekoo-jade nile kewu,eyi tawon larubawa n pe ni Walimotul Quran. Ojo naa nilekewu naa toruko e n je 'Markazul Hikmahwal Hidayah' labe Fadilatul Ustaz Abdu Hakeem Adeshina Aremu Balogun yoo fun Abdulmalik niwe eri pe o kekoo-jade nile-kewu yii.
Awon alejo pataki ti won n reti nibi ayeye yii ni: Alayeluwa Oba Abdulgafar Olasunkanmi Adisa Tijani Alawowo tillu Awowo-Oriloye Gbadewolu 1, Alaaji Oloye Mutairu Akanni Owoeye, Alaaji Abdul Fatah Akanni Shobowale, Alaaji Kola Oladepo, Alaaji Oloye Ibrahim Olaniyan, Alaaji Mogaji Moshood Gbolagade, Alaaji Jamiu Abiodun Moshood.
Awon baba ojo naa ni: Alaaji Abdulrasheed Iyanda Adetona, Alaaji Babatunde Jinadu Elesho, Alaaji Najeemdeen Olatokunbo Korodo, Alaaji Abdul Ganiyu Owolabi , Alaaji Wasiu Kuforiji, Alaaji Mutiu Olaide Oladebo, Alaaji Onarebu Abdul Rafiu Yakubu, Onarebu Abdulganiy Babatunde Aweda, Alaaji Ishaq Olufemi Omowunmi, Alaaji Abdul Azeez Akanbi Oladokun.
Awon iya ojo naa ni:Alaaja Idayat Bola Muse, Alaaja Abiola Shobowale, Alaaja Tawakalitu Oladosu, Alaaja Motunrayo Agoro, Seyyidat Nuriyat Ekemode Coker. Lara awon alejo pataki ojo naa ni:Alaaji Mikaeel Adeyinka Jimoh , Alaaji Yusuf Olatunji Lawal, Alaaji Taofeek Omotolani, Alaaji Ambali Taiwo Shodunke, Dokita Ambrose Olutayo Shomide, Oloye Abbey Fagboro, Alaaji Bashir Adisa Baba Gboin, Alaaji Ridwanulahi, Dokita Yomi Mate Ifankaleluyah.
Awon alga ojo naa ni: Alaaji Olayinka Quadri, Alaaji Babatunde Saheed Oluomo Kutonu, Alaaji Musibau Alade Jimoh, Alaaji Isiaq Oladiti, Alaaji Otunba Sulaiman Adele Muhammad, Al-Yusuf International Travel and Tours, Alaaji Abdulwaheed Ishola Adekoya, Alaaji Abdulwasiu Olatoye ati Alaaji Abdul Lateef Balogun.
Awon alaga obinrin ojo naa ni:Oloye Yetunde Babajide,Alaaja Hamdalat Olokuta,Alaaja Bislam Fabric,Alaaja Aishat Olayemi Ajide Olayinka, Oloye Olatokunbo Skin Dudu,, Alaaja J.J Ajoke Mama J, Alaaja Hafsat Ademolu Alausa, Alaaja Wakilat Ayomide Jimoh ati Remilekun Balogun.
Awon alejo pataki ni: Alaaji Ishaq Olayinka Emi-Abata, Alaaji Abdul Hakeem Idowu Olomitutu, Alaaji Abdulwahab Ogunji Ajere, Alaaji Soliu Oluwaponmile Adesanya, Alaaja Oluwa, Alaaja Abiola Olaniyan, Alaaja Serifat Abati, Alaaji Mikael Bukhary, Alaaji Sufyan Adebayo, Alaaji Saoban Oladipupo, Ogbeni Jubril Bankole, Ogbeni Ibraheem Ogunlade, Alaaja Rasheedat Bukhary, Alaaja Adebayo Mama Kebe, Alaaja Samiah Yusuff, Alaaja Safurat Bello, Alaaja Sherifat Mama Fufu, Alaaja Adebayo Mummy Islamiyat, Alaaja Sekinat Folarin, Alaaja Qudirat Taiwo, Ogbeni Abolade Mummy Aminat Iyalaje 1, Ogbeni Hussan Daddy Rafiah, Ogbeni Yufuff Daddy Rashidat, Ogbeni Jimoh Daddy Zainab, Ogbeni Olokodana ati Ogbeni Soliu Daddy Aishah,
Fun alaye lekunrere, e pe Alaaja Asani sori nomba yii:08056901479
Thursday, 18 October 2018
Home
/
IROYIN
/
ORO TO N LO
/
OPE O, ABDULMALIK, OMO ALAAJA KUDIRAT ASANI, GBAJUMO SOROSORO FEE SE WOLIMAT
OPE O, ABDULMALIK, OMO ALAAJA KUDIRAT ASANI, GBAJUMO SOROSORO FEE SE WOLIMAT
Nipa IROYIN OJUTOLE
NJE O NI IROYIN FUN WA BI? TABI O NI AYEYE TI O FE KI A BA O GBE JADE? ABI IPOLOWO OJA TABI IKEDE LE FE SE, TETE PE SORI AWON NOMBA WONYI: 08023939928, 08185819080.
ORO TO N LO
Tags
IROYIN,
ORO TO N LO
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment