Leyin aisan to se e, ti won si gbe e lo sile iwosan ijoba 'UCH' to wa niluu Ibadan, agba-oje osere tiata Yoruba nni, Alagba Ola Omonitan tawon eeyan mo si Ajimajasan tabi Baba No Regret ti ku o.
Aaro yii ni baba naa jade laye nilewosan ijoba yii. Latigba ti baba naa ti dake lawon eeyan, paapaa awon osere ti n daro e.
Fawon ti ko ba ranti mo, okunrin yii lo kopa Baba No Regret ninu ere ori telifisan olosoose to maa n waye lori telifisan NTA ti won pe ni 'Iya Ibeji Omo Araaye le'.Gbogbo bi eto isinku baba yii ba se fee lo la o fi to yin leti.
Thursday, 18 October 2018
O MA SE O, AJIMAJASAN ONITIATA TI KU O
Tags
# LAGBO OSERE
Nipa IROYIN OJUTOLE
NJE O NI IROYIN FUN WA BI? TABI O NI AYEYE TI O FE KI A BA O GBE JADE? ABI IPOLOWO OJA TABI IKEDE LE FE SE, TETE PE SORI AWON NOMBA WONYI: 08023939928, 08185819080.
LAGBO OSERE
Tags
LAGBO OSERE
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment