IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Thursday, 11 October 2018

O MA SE O, ARA AJIMAJASAN ONITIATA KO YA GIDIGIDI, WON N WA IRANLOWO OWO FUN UN



Asiko yii ki i se asiko kan gidi fun agba-oje osere tiata Yoruba, to tun je aderin-in-po- sonu atawon ebi e, Alagba Ola Omonitan tawon eeyan tun mo si Ajimajasan tabi Baba No Regret pelu bi aisan nla se  da okunrin naa gunle. 
Ileewosan UCH to wa niluu Ibadan, nipinle Oyo la gbo pe baba to  kopa pataki ninu ere ori telifisan 'Omo Araye' naa  wa to ti n gbatoju lowo bayii.

Bakan naa la gbo pe ibi ti aisan naa lagbara de, awon ebi n wa iranlowo owo fun un, ti won ko ba si tete rowo yii afaimo lohun ti won lero ko ni i sele.

Enikeni to ba fee ran Baba yii lowo, ko pe awon omo e, Rotimi Omonitan sori 
nomba yii: 08062088182 tabi ko pe  Anike sori:

0816818134, 

No comments:

Post a Comment

Adbox