IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday, 14 September 2018

ONI LOJOOBI EEYAN WA, GBAJUMO OLORIN EMI, AYANFE JESU

Gbogbo wa nileese Ojutole la ki eeyan wa daadaa, Efanjeliisi Stella Elegbeleye ti gbogbo aye mo si Ayanfe Jesu, fun ayeye ojoobi e to waye loni-in. Adura wa ni pe komo olojoobi s
opo odun laye ninu ola, owo ati alaafia to peye.

Igba odun, odun kan ni fun eeyan wa.

No comments:

Post a Comment

Adbox