IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday, 21 September 2018

ONI LOJOOBI ASIWAJU BUSARI ABOLORE, E JE KA SE GBOSA META FUN OGA OLOPAA

Gbogbo wa pata nileese Ojutole la ki eeyan wa daadaa. Asiwaju Busari Abolore ku ayeye ojoobi won to waye loni-in. A gba a ladura fun oga olopaa to moye, oga olopaa to mose, oga olopaa to gallant pe opo odun ni won yoo se laye.

E ko ni i faisan logba, idaamu aye ko ni i je ti yin, e ko ni i ri wahala lenu ise, igbega nla, igbega alalubarika la toro fun yin lenu iseHapi Batide sa.







.

  

No comments:

Post a Comment

Adbox