Ilu Arigbajo Ifọjọ, Ifo, ipinle Ogun yoo gbalejo obitibiti awon eeyan pataki lawujo lojo kẹsan-an, ọṣu Kejila odun yii, idi nipe ojojo yii ni Oloye Ifayomi Babatunde yoo se aasekagba odun ifa eleekesan-an.
Ọba Orin, King Dr Saheed Osupa ati Alhaji Tọpẹ Nautical ni yoo sere fawon ololufe ifa Lati ojo keje si ojo kesan- an layeye yii yoo fi waye,e .
Gbogbo eyin ololufe ifa ni obaedu pe sibi odun ifa ti odun yii boya eyin fee mo nipa ayeye odunfa yii tabi e fe beere nipa igbesi aye yin e pe nomba yii:08020587706
No comments:
Post a Comment