Gbogbo adugbo Rafco nitosi MAO ni Alagbado ipinlẹ Eko yoo mi titi lọjọ Aiku, Sannde, iyẹn ọjọ kẹta oṣu Kejila, ọdun yii
Oloye Toriọla yoo gbalejo awọn eeyan gidi sibi ayẹyẹ ọdun ifa ẹ, Alaaji Sule Alao Malaika ni yoo dalubolẹ lọjọ naa nigbati Okele,Baraka ati Koyokoyo yoo tukọ eto.Boya ẹ ni ibeere tabi ẹ fẹ beere nipa igbesi aye yin,e pe oloye Ọpeifa si 08034085454
No comments:
Post a Comment