IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday 2 July 2023

Gongo so nìbi ayeye Ojude Oba ilu Ibeju



Yoo pe e daadaa kawon omo ati ara ilu Ibeju, nipinle Eko, too gbagbe ojo Eti, Furaidee to koja yii, idi nipe ojo naa ni won se ayeye Ojude Oba tilu naa.

Kaakiri ibi tawon omo bibi  ilu isembaye naa wa ni won ti wa sile fun ayeye naa, eyi to je akoko iru e. Oba ilu Ibeju lapapo, Alayeluwa Oba Rasaki Olasunkanmi Waliu Oguntolu Akoko lo gba gbogbo eeyan lalejo


Inu ogba  ileewe Ibeju Town Primary School layeye nla ohun ti waye

Orisiirisii eto lo waye lọjọ naa lati je ki odun naa larinrin, lara e ni ijo tawon obinrin ilu naa jo atawon ohun asa ilu Ibeju mi-in.


Lara oba to wa nìbi ayeye naa ni:Oba Onisolu tiluu Solu Alade,Olu Kayetoro tiluu  klKayetoro ati Oba  Ogunfayo.

Ohun to daju saka nipe ojo naa dun, bee lo tun larinrin.

No comments:

Post a Comment

Adbox