IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Monday 3 April 2023

Ope o: Gbajugbaja Olorin emi, Oba Ara ra boosi boginni fawon omoose e


Iroyin to te wa lowo latodo Gbajugbaja Olorin emi nni, Efanjeliisi Michael Oluwarotimi Onimole Oba Ara ni pe osere nla omo bibi ilu Eko naa sese ra moto boosi boginni fawon omoose e ni.

Ni nnkan bi ojo meloo kan ni irawo akorin emi naa ja ora lara moto olowo nla naa. Idunnu la gbo pe o subulayo nigba tawon Iko orin e foju kan moto naa

No comments:

Post a Comment

Adbox