IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday 7 September 2022

Gongo so lojo ti oga-agba ileese Al-Yusuf Travel And Your Limited di Turaki Adinni L'Ekoo

Gongo so lojo ti oga-agba ileese Al-Yusuf Travel And Your Limited di Turaki Adinni L'Ekoo


Ojo nla ti oga-agba ileese Al-Yusuf Travel and Tours limited, Alhaji Abdulmojeed Ajadi  Yusuff ko le gbagbe boro lojo Aiku, Sannde to koja yii, idi nipe ojo naa ni ijo Zawiyat Tijaniyat fi okunrin naa joye Turaki Adinni gbogbo Tijaniyat ni Itire ati agbegbe re

Ayeye oye ohun to waye ni papa isere National Stadium to wa ni Surulere lawon eeyan jankanjakan lawujo ti fi ijokoo ye gbajumo onisowo naa si.

Ilu mo on ka olorin Islam nni, Alhaja Misturah Amoke Aderounmu Ashafa ti gbogbo aye mo si Temi ni success lo forin da awon eeyan lara ya lojo naa.



No comments:

Post a Comment

Adbox