IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday, 3 July 2022

Won si n wa owo itoju fun gbajumo produsa awon olorin, Ademola Adelakun



Bo tile je pe awon eleyinju aanu omo orileede yii kan ti dide iranlowo si gbajumo produsa awon olorin, Omooba Ademola Adelakun ti ara re ko ya, sibe owo nla ni won si nilo fun itoju okunrin olopolo pipe naa.

Bayii, milionu marun-un Naira lowo ti awon eeyan ti fi ran  okunrin naa lowo bayii, sugbon milionu lona ogun Naira, iyen 20 millions Niara  lowo ti won wa fun un.

Nibi ti oro de duro bayii, awon alamoojuto eto ikowojo naa ti rawo bee si gbogbo omo orileede yii lati ran okunrin naa lowo, ki owo ti won n wa fun itoju ti Adelakun fee loo se lorileede Germany yii le e pe

E jowo, e ba wa ran Ademola Adelakun lowo, aisan ko ni  se gbogbo wa o



Eni to ba fee ran okunrin naa lowo, e fi ohun ti e ba fee fun un sinu akanti yii.ACCT NAME: Adelakun Olubukola Olufisayo 

ACCT NUMBER: 0431383423 

BANK: GTBank 

No comments:

Post a Comment

Adbox