IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday, 15 March 2022

Oni layeye ojoobi Alaaji Idowu Amaao, Alakooso egbe Sidophobia Fans Club lOyoo




Oni ojo keeedogun osu keta ni gbajugbaja onisoowo nni, to run je alakooso patapata fun egbe Sidophobia Fans Club nipinle Oyo.

Latigba tile ti mo lawon eeyan ti n ki okunrin naa ku oriire ayeye ojoobi odun kejidinlogota to pe laye.

Awon ara, ebi, ore atawon afenifere ni won ti n ki Alaaji Amaoo ku oriire pe o le odun kan loke eepe. Nitori ipa nla ti okunrin yii ko fun idagbakoke egbe orin gbajugbaja akorin, Alaaji Abass Akande Obesere Agbaakin Abobagunwa gbogbo ile Yoruba lo je ki won yan an sipo naa.

Adura wa fun Alaaji Amao ni pe ki won se opolopo odun laye ninu ola, owo, alaafia to peye ati igbega repete. Hapi batide. 

No comments:

Post a Comment

Adbox