IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Monday, 14 March 2022

Ayeye Ojoobi, Esi Adura ki MC Oluomo Ku Oriire


Okan gboogi ninu awon olori egbe onimoto nipinle Eko, to tun je onisowo pataki, Alhaji Ismaila Issa ti gbogbo aye mo si Esi Adura Otitoloju ti ranse ikinni ku oriire ayeye ojoobi si Alaga egbe onimoto nipinle Eko, Alaaji Musiliu Ayinde Akinsanya Oluomo.

Ninu prove, Esi Adura ni mo fi asiko yii ki oga wa, egbon wa, baba wa, Alhaji Musiliu Ayinde Akinsaya fun ayeye ojoobi won to waye loni-in, adura mi fun won ni pe ki Olorun je ki won se opo odun laye ninu ola, owo, ilosiwaju ati alaafia to peye.

 A jo se todun to koja ni, a se todun yii lagbara Olorun to ba di odun to n bo, won ko ni I fi kuliwualahu ranse si yin.

No comments:

Post a Comment

Adbox