Bi osu aawe alaponle, iyen ramadan se wole bo diedie, Aare egbe Strong Women kari aye, Alhaja Baliqees Ashabi Abiodun Hassan n ki gbogbo musulumi ododo fun imurasile osu abinyin naa
Ninu oro akinkaju ati ojogbon obinrin to fi orileede Amerika sebugbe lo ti so pe mo fi asiko yii ki gbogbo musulumi kari aye, paapaa, awon omo egbe Strong Women ku imurasile osu ramadan, osu laadaa. Olorun yoo je ko ba wa laye ati aaye gidi, ki Olorun Allah ma se dun wa ni gbogbo laadaa ati oore to wa ninu osu naa.
Alhaja Kudirat Ashani Erioso lo sagbateru ikinni yii

No comments:
Post a Comment