Ogunjo osu keji odun yii lobinrin naa fee sayeye asekagba oku mama e, Mama Fausat Aduke Mopelola Olonade.
Gbajumo olorin Islam nni, Hajia Muinat Iya Cairo ni yoo forin aladun da awon eeyan lara ya lojo naa.
Awon eeyan jankanjankan ni won reti nibi ayeye naa. Ankara lawon eeyan yoo fi wole sibi ayeye yii.
No comments:
Post a Comment