IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 16 December 2020

Owo OPC te awon janduku to n ko idaamu ba awon ara Agege

Owo awon omo egbe Oodua Peoples Congress, OPC, eka Agege ti te awon janduku kan ti won ma a n ja awon olugbe Agege ati agbegbe e lole labe biriiji elese to wa ni Agege.

Ale ana lowo te awon afunrasi odaran yii pelu ifowosowopo awon omo egbe awako NURTW eka Agege.

Ilukulu ni won koko fi awon janduku naa ti ojo ori won ko ju Ogun odun lo se, ko too di pe won fawon le awon olopaa lowo fun iwadii to peye.

Se ninu awon ara Agege dun pe owo ti te die ninu awon eeyan ti won n ja awon lole.

No comments:

Post a Comment

Adbox