Gbajugbaja osere tiara Yoruba nni, Lateef Adedimeji, ti jewo pe eru koko ba oun nigba ti Tunde Kelani so pe oun loun yoo kopa gege bii baba awon olorin apala to doloogbe, Waheed Anigilaje ti gbogbo aye mo si Ayinla Omowura ninu fiimu ti won pe oruko re ni Ayinla.
Okunrin yii, lasiko to n ba telifisan Alaroye soro, lo ti so pe aya oun koko ja, ti kinni ohun ka oun laya lojo akoko tawon de oko ere naa. O lo fee to igba meedogbon ti won fi ya oun ko too di pe kinni ohun pada bo si oun lowo gege bii Tunde Kelani to ko fiimu naa se fe.
Bakan naa lo fi kun pro e pe owo nla loun gba lati kopa Ayinla Omowura, sugbon o ko lati so iye to gba fawon Alaroye.
No comments:
Post a Comment