IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 30 December 2020

Adewọle Alao, onilu Ayinla Ọmọwura, ti ku o

Okan gboogi ninu awon onilu Oloogbe Ayinla Omowura, iyen Alaaji Adewole Alao Onilu Ola, ti dagbere faye.

Eni odun metadinlogorun ni baba naa kolojo too de
Titi aye lawon ololufe orin yoo maa ranti baba yii fun ipa nla to ko fun idagbasoke egbe orin Eegunmogaji. Ki Olorun te baba olopolo pipe naa si afefe ire.

No comments:

Post a Comment

Adbox