Se ni gbogbo ilu yii kun fun awon eeyan pataki lawujo, moto boginni ni won ko wo ilu naa.
Bee ni gbajugbaja olorin omo orile-ede yii, sugbon to fi orile-ede Amerika sebugbe, Oloye Yinka Al-Hassan ti gbogbo aye mo so Yinka Rtyhms tabi Somebody naa se bebe, awon ebi e, eyi ti mama e, Alaaja Bolanle Ibraheem Onigbanjo saaju won lo ran lo si Ipokia lati ba kabiyeesi tuntun naa yo ayo igbade.
Ebun nla lawon ebi Mr.Somebody fi ta Onipokia lore
Ojutole naa wa nibe lati mu aworan ayeye igbade naa wa fun yin.
No comments:
Post a Comment