Gbogbo eto loti pari lori waasi aawe ramadan olodoodun tawon ololufe gbajumo olorin Islam nni, Hajia Shukurat Adeola ti gbogbo aye mo si Akobi Ayeloyun, iyen 'Akobi Ayeloyun Fans Club' pelu ifowosowopo Otunba Eniyan fee se. Ojo Tosde, ojo ketalelogun, osu, yii ni waasi naa yoo waye ni Abule-Iroko Prayer Ground, Last Bus-stop, ipinle Ogun. Eni ti yoo se waasi lojo naa ni Fadlak Sheik Abd-Rahman Solahudeen Buhari Keji. Yato si waasi yii, won yoo tun sayewo ofe fawon eeyan, eyi ti Onarebu Yusuff Adegbemiro sagbateru e. Akole waasi odun yii ti yoo je eleeketa iru e ni won pe ni 'Reality in Islam'
Friday, 17 May 2019
OJO TOSDE TO N BO NI WAASI AAWE RAMADAN AKOBI AYELOYUN YOO WAYE
Tags
# ORO TO N LO
Nipa IROYIN OJUTOLE
NJE O NI IROYIN FUN WA BI? TABI O NI AYEYE TI O FE KI A BA O GBE JADE? ABI IPOLOWO OJA TABI IKEDE LE FE SE, TETE PE SORI AWON NOMBA WONYI: 08023939928, 08185819080.
ORO TO N LO
Tags
ORO TO N LO
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment