IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday 13 February 2019

ONI LAYEYE OJOOBI BASANYA OLAMILEKAN, A BA EEYAN WA DAADAA DUPE LOWO OLORUN

Gbogbo  wa pata la ba eeyan wa daadaa, Olamilekan Basanya ti gbogbo aye mo si Old Skool dupe lowo Olorun fun ojoobi e to waye loni-in.

Adura wa ni pe ki omo olojoobi sopo odun laye ninu ola, owo ati alubarika to repete. Igba odun,iseju aaya ni. 

No comments:

Post a Comment

Adbox