Gbogbo wa pata nileese Ojutole ka ki eeyan wa daadaa, gbajumo akorin Islam nni, Alaaja Mufuliat Kolawole Mojere, ku oriire ayeye ojoobi e to waye loni-in. A gba a ladura pe omo olojoobi yoo sopo odun laye ninu ola,owo, alubarika ati igbega to dara.
Gbogbo wa pata nileese Ojutole ka ki eeyan wa daadaa, gbajumo akorin Islam nni, Alaaja Mufuliat Kolawole Mojere, ku oriire ayeye ojoobi e to waye loni-in.
Nipa IROYIN OJUTOLE
NJE O NI IROYIN FUN WA BI? TABI O NI AYEYE TI O FE KI A BA O GBE JADE? ABI IPOLOWO OJA TABI IKEDE LE FE SE, TETE PE SORI AWON NOMBA WONYI: 08023939928, 08185819080.

No comments:
Post a Comment