Iroyin aburu to te wa lowo latodo awon olorin juju ni pe agba-oje olorin juju nni, Great Ade Samson, ti jade laye, bee ni won ti sinkuu e lojo Aiku, Sannde to koja yii.
Gege bi a se gbo, aisan kan lo ki okunrin naa mole, eyi to pada gba emi e. Bakan naa la gbo pe ojo Eti, Fraide to koja lohun un ni won sayeye ogoji odun fun un, ti baba naa si ku lojo keta ayeye yii.
Gbogbo awon eeyan ti won mo baba yii ni won sapejuwe e bii eeyan daadaa, won ni ki i woju pa awon omode re, bee lo mose orin yii doju ami.
Ki Olorun fori ji Great Ade Samson, ko pa gbogbo ese re re.
Friday, 12 October 2018
O MA SE O: GREAT ADE SAMSON OLORIN JUJU TI KU O
Tags
# LAGBO OSERE
Nipa IROYIN OJUTOLE
NJE O NI IROYIN FUN WA BI? TABI O NI AYEYE TI O FE KI A BA O GBE JADE? ABI IPOLOWO OJA TABI IKEDE LE FE SE, TETE PE SORI AWON NOMBA WONYI: 08023939928, 08185819080.
LAGBO OSERE
Tags
LAGBO OSERE
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment