IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday, 12 October 2018

BARRYSHOWKEY, SAFEJO AMAMA ATAWON OLORIN MI-IN YOO FORIN DABIRA NIBI AYEYE IRINSE TUNTUN TI MAYOR ADEWALE ALAMU FEE SI


 .


Gongo yoo so lojo kerinla, osu kejila, odun yii, ojo naa ni gbajumo olorin fuji nni, Mayor Adewale Alamu yoo sefilole irinse olowo nla to sese ra. Gbongan  15000 Belliare Blvd, to wa ni Houton Texas 77083, lorile-ede Amerika layeye naa yoo ti waye.

Die lara awon irawo olorin ti won yoo forin aladun da awon eeyan laraya lojo naa ni: Seriki Adewale Akani Balogun ti gbogbo aye mo si  Barryshowkey,  Oga nla 2 Safejo Amama, Dele Thomas,  Femi Johnson,  Bimbola Taloba, Mr. Sugar atawon mi-in.Awon ti yoo dari ayeye naa ni: Mc Daddy Cool ati Omoge Ibadan. Ileese  First Omega Entertainment lo sagbateru e

No comments:

Post a Comment

Adbox