Fawon ti ko ba ti i gbo, akobi gbajumo osere fuji Taye Adebisi Currency,iyen Yusuff Oladeni naa ti gba foomu lati dije ninu egbe oselu PDP gege bii asofin nile igbimo asofin ipinle Oyo.
Awon eeyan Iwo-Orun ilu Ibadan lomokunrin naa fee loo soju fun nile igbimo asofin. Ijeta ode yii lo loo gba foomu lati dije ninu ibo abele egbe oselu PDP.
Bakan naa ni Ojutole gbo pe gbogbo ona ni baba e, Taye Currency n sa lati ri i pe omo e
lo wole ibo to n bo lodun 2019 yii.
No comments:
Post a Comment