
Ohun ti Ojutole gbo ni pe awon ara Epe ti Ambode ti wa so pe awon ko gbodo ri gbajumo osere fuji naa nilu awon mo, won ni to ba se e si wa si Epe, ko ni i faraare lo.
Nibi ti oro yii bi awon eeyan yii ninu de, won tun leri pe awon ko ni i gbese orin fun K1 mo, gbogbo ona lawon yoo si gba lati ri i pe awon ore awon paapaa koyin si osere omo bibi ilu Ijedu-Ode yii.
Ohun tawon eeyan yii so ni pe ohun ti Wasiu Ayinde se yii, ki i se Ambode nikan lo kan labuku,gbogbo ara Epe ni,nitori pe asoju awon gidi l'Ambode n se.
Ju gbogbo e lo, awon ara Epe n binu si Oluaye awon onifuji,won si ti leri pe awon yoo ba a mu nnkan nile to ba wa s
iluu awon.
No comments:
Post a Comment