E gbo bo se wi 'Mi o le gbagbe iru iya nla to je mi nigba ti mo bi Michelle, gbogbo nnkan ini mi pata ni mo ta ni Yabaa ka le e rowo jeun, atowo ileewe e. Oju mi ri to, mo je moyo iya.'

Fawon ti ko ba mo, ileewe yunifasiti 'UNILAG' ni Mercy wa to fi bi akobi e yii, sugbon awon obi okunrin to bimo fun yii ko gba ki won fera. Ohun to fa a niyen to fi je pe osere yii nikan lon da gbo bukaata omo e yii.
Leyin opolopo odun lo pade okunrin oloteeli ti won n pe ni Larry Gentry, omo kan lo bi fun oun naa
kaarin won too daru.
No comments:
Post a Comment