IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday, 22 September 2018

IROYIN YAJO-YAJO: OGAGUN BAMIGBEOYE, GOMINA IPINLE KWARA TELE TI KU O

Gomina ipinle Kwara tele, Ogagun-feyinti, Femi David Lasisi Bamigboye ti jade laye, leni odun mejidinlogorin
Omo bibi ilu  Omu Aran, nijoba ibile ni Ifelodun ni Oloogbe, aburo lo je fun Ogagun Theophilus Bamigboye.
Laarin odun 1967 si odun 1975, ni Bamigboye fi se gomina ipinle Kwara. Odun 1940 ni won bi i, oun lo da eka eto eko sile nipinle Kwara, bee lo seto igbimo ti yoo ma a fun awon akekoo ileewe giga lowo ajemonu ti won n pe ni bursary.

No comments:

Post a Comment

Adbox