Okan lara awon agba-oje elere ori itage ile wa, to loruko daadaa ni Gbenga Adebayo Oladunni tawon eeyan mo si Imalian Boy.
Ohun ti Ojutole gbo ni pe osere to fi ilu Abeokuta, nipinle Ogun, sebugbe yii naa ti bere ipolongo lati di asofin nile igbimo asofin ipinle naa. Awon eeyan iku idibo Ariwa Abeokuta lo fee loo soju fun
Egbe oselu ACCORD la gbo osere to tun je sorosoro ori radio yii ti jade lati dupo oselu.
Bakan naa ni won fi to wa leti o ti n sa gbogbo ipa e lati ri i pe oun lawon eeyan ilu Abeokuta dibo fun lasiko ibo odun 2019 to n bo yii.
No comments:
Post a Comment