IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 1 August 2018

Ojo nla lojo ti gbajumo osere fuji, Akeem Adewale Alamu segbeyawo alarinrin pelu Afolashade l'Amerika

Laipe yii ni gbajugbaja osere fuji to fi orile-ede Amerika sebugbe, Mayor Akeem Adewale Alamu segbeyawo pelu ololufe e, Arabinrin Elizabeth Afolasade Lawal.

Bamubamu lawon eeyan pataki,awon olola,awon otokulu atawon afenifere kun gbongan tayeye igbeyawo naa ti waye.

Gbajumo osere fuji nni, Alaaji Mudasiru Ajani Safejo Amama lo korin nibi ayeye igbeyawo yii.

Die ninu awon foto ti won ya lojo naa niyii.














No comments:

Post a Comment

Adbox