Gbogbo awa osise ileese www.ojutole.com, iroyinojutole-toko ati ojutole online tv la ki ore wa daadaa, Taiwo Rasheedat Raji ku oriire ojoobi e to waye loni-in.
A gba a ladura pe ki Ejire Omo Oba sopo odun laye,
ki Edunjobi dagbadagba, ko ma fi aisan logba, ko ma fi ibanuje lo ile aye.
Igba odun,iseju aaya ni fun ore wa to sha proper, Edun a gbo igi rekereke to sha prahprah
Wednesday, 1 August 2018
E je ka ba Taiwo Raji dupe Olorun, oni lojoobi ore wa atata
Tags
Nipa IROYIN OJUTOLE
NJE O NI IROYIN FUN WA BI? TABI O NI AYEYE TI O FE KI A BA O GBE JADE? ABI IPOLOWO OJA TABI IKEDE LE FE SE, TETE PE SORI AWON NOMBA WONYI: 08023939928, 08185819080.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)



No comments:
Post a Comment