IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday 5 March 2024

Ijo Genesis Global bere isoji olojo meje

Ijo Genesis Global eka ti isheri gbe eto isoji alagbara fun ojo meje kale,nibi ti ogun aye yii yoo ti wole lo pelu agbara adura,

Isoji alagbara to ti bere lojo Monde ose yii yoo pari lojo Sunday iyen ojo ibi oluso Oladele Ogundipe Genesis,ijo won to wa niGenesis bustop Igando rd along Lasu nitosi Agric  estate ,iwaju petrocam petrol station isheri ni Olorun ti n gba owo wolii re sise ami ati ise iyanu.
 Prophet Akinola Fashawe yoo wa nibe pelu ,olugbalejo agba ni oluso Oladele Isreal Genesis tawon olorin emi bii: Abbey Awesome,Dare Oxygen ati Samuel Daramola naa yo wa nibe.
Fun ekunrere alaye e pe 08039403425 Jesu n duro de o

No comments:

Post a Comment

Adbox