IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday, 11 December 2022

Gongo so lojo ijo Igathatullahi sayeye odun kefa, ojoobi Anobi ati fifun awon eeyan lami-eye


    
Ana ojo kokanla osu kejila odun yii ni  Igathatullah labe oludasile won, Sheik Giyasullahi Abiola Agoro sayeye odun kefa ti won da ijo naa sile, bee ni won tun fun awon eeyan lami-eye

   Lati gberi okun lawon eeyan ti wa, tawon ti gberi osa papaa, ko riyeriye debe, won waa ba omo baba Agoro, to ba keu nile, toun paapaa tun gbiyanju ka quraani oun imo larubawa daadaa seye ojoobi Muhammad.

Orisirisisi bii aso onisuga lawon eto to waye o, idije kuraani, fifi ami eye da ni lola, bee ni odomode onimo kuraani, to n se bii agbalagba, sheik Abdul Rahman Olanbiwoninu Foreign   se waasi.
Die ninu awon eeyan ti won wa nibe lojo naa ree

No comments:

Post a Comment

Adbox